PEN YORÙBÁ: ÌWÀ ÌBÀJÉ NÍ ORÍLÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ ÀTI NÍ ÀGBAYÉ
Láti Ọwọ́ Oyekanmi Abdulwarith Ayomide Nàìjíríà jẹ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀, ilẹ̀ Nàìjíríà (Nigeria ni èdè Gẹ̀ẹ́sì) jẹ́ orílẹ̀-èdè ìjọba àpapọ̀ olómìnira tí ó ní ìjọba ìpínlẹ̀ mẹ́rindínlógójì ,tó fi…